Joshua 17:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé àwọn ọmọbinrin Manase gba ilẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ìbátan wọn tí wọ́n jẹ́ ọkunrin. Wọ́n pín ilẹ̀ Gileadi fún àwọn ọmọ Manase yòókù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti awọn ọmọbinrin Manasse ní ilẹ-iní lãrin awọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin: awọn ọmọ Manasse ọkunrin iyokù si ní ilẹ Gileadi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí àwọn ọmọbìnrin ẹ̀yà Mànásè gba ìní ní àárin àwọn ọmọkùnrin. Ilẹ̀ Gílíádì sì jẹ́ ti ìyókù àwọn ọmọ Mánásè.