Joshua 17:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Manase ni wọ́n ni ilẹ̀ Tapua, ṣugbọn ìlú Tapua gan-an, tí ó wà ní ààlà ilẹ̀ àwọn ọmọ Manase, jẹ́ ti àwọn ọmọ Efuraimu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Manasse li o ní ilẹ Tappua: ṣugbọn Tappua li àla Manasse jẹ́ ti awọn ọmọ Efraimu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(Mánásè lo ni ilẹ̀ Tápúà, ṣùgbọ́n Tápúà fúnra rẹ̀ to wa, ni ààlà ilẹ́ Mánásè jẹ ti àwọn ará Éfúráímù.)