Joshua 19:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ kẹta tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Sebuluni. Agbègbè tí ó jẹ́ ìpín tiwọn lọ títí dé Saridi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ kẹta yọ fun awọn ọmọ Sebuluni gẹgẹ bi idile wọn: àla ilẹ-iní wọn si dé Saridi:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gègé kẹ́ta jáde fún Sébúlunì, ní agbo ilé ní agbo ilé: Ààlà ìní wọn sì lọ títí dé Sárídì.