Joshua 19:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ kẹrin tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Isakari.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ipín kẹrin yọ fun Issakari, ani fun awọn ọmọ Issakari gẹgẹ bi idile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gègé kẹrin jáde fún Ísákárì, agbo ilé ní agbo ilé.