Joshua 19:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lórí ilẹ̀ náà ni àwọn ìlú wọnyi wà: Jesireeli, Kesuloti, Ṣunemu;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Àla wọn si dé Jesreeli, ati Kesuloti, ati Ṣunemu;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lára ilẹ̀ wọn ni èyí: Jésíréélì, Késúlótì, Súnemù,
Recommended Reading