Joshua 19:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ìlú tí ó wà ninu ilẹ̀ tí wọ́n pín fún wọn nìyí: Beeriṣeba, Ṣeba, Molada;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si ní Beeri-ṣeba, tabi Ṣeba, ati Molada, ni ilẹ-iní wọn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lára ìpín wọn ní: Béérí Ṣébà (tàbí Ṣẹ́bà), Móládà,