Joshua 19:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ karun-un tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Aṣeri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ipín karun yọ fun ẹ̀ya awọn ọmọ Aṣeri gẹgẹ bi idile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gègé karùnún jáde fún ẹ̀yà Áṣíérì, ní agbo ilé agbo ilé.