Joshua 19:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Uma, Afeki, ati Rehobu wà, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mejilelogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Umma, ati Afeki, ati Rehobu: ilu mejilelogun pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Úmà, Áfẹ́kì àti Réóbù. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlélógún àti ìletò wọn.