Joshua 19:40 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ keje tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Dani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ keje yọ fun ẹ̀ya awọn ọmọ Dani gẹgẹ bi idile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbò keje jáde fún ẹ̀yà Dánì, ní agbo ilé ní agbo ilé.