Joshua 2:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọkunrin náà sọ fún Rahabu pé, “A óo mú ìlérí tí o mú kí á fi ìbúra ṣe fún ọ ṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọkunrin na wi fun u pe, Ara wa o dá niti ibura rẹ yi, ti iwọ mu wa bú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn arákùnrin náà sì sọ fún un pé, “Kí ọrùn un wa baà lè mọ́ kúró nínú ìbúra tí ìwọ mú wa bú yìí.