Joshua 2:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn bí o bá sọ ohun tí a wá ṣe fún ẹnikẹ́ni, ẹ̀bi ìlérí tí a fi ìbúra ṣe yìí kò ní sí lórí wa mọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi o ba si sọ ọ̀ran wa yi, nigbana ni ara wa o dá niti ibura rẹ ti iwọ mu wa bú yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n bí ìwọ bá sọ ohun tí àwá ń se, àwa yóò bọ́ nínú ìbúra tí ìwọ mú wa bú.”