Joshua 21:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ati àwọn ìlú wọnyi pẹlu àwọn pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn: Jatiri, Eṣitemoa,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Jatiri pẹlu àgbegbe rẹ̀, ati Eṣtemoa pẹlu àgbegbe rẹ̀;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Játírì, Ésítẹ́móà,