Joshua 21:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aijaloni ati Gati Rimoni, gbogbo wọn jẹ́ ìlú mẹrin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aijaloni pẹlu àgbegbe rẹ̀, Gati-rimmoni pẹlu àgbegbe rẹ̀; ilu mẹrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áíjálónìd àti Gati-Rímónì, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn jẹ́ mẹ́rin.