Joshua 21:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ilẹ̀ ẹ̀yà Aṣeri, wọ́n fún wọn ní: Miṣali, Abidoni,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu ẹ̀ya Aṣeri, Miṣali pẹlu àgbegbe rẹ̀, Abdoni pẹlu àgbegbe rẹ̀;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ara ẹ̀yà Ásíérì ni wọ́n ti fún wọn ní Mísálì, àti Ábídónì,