Joshua 21:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ilẹ̀ ẹ̀yà Gadi, wọ́n fún wọn ní: Ramoti ní Gileadi. Ramoti yìí ni ìlú ààbò fún àwọn tí wọ́n bá ṣèèṣì pa eniyan. Wọ́n tún fún wọn ní Mahanaimu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu ẹ̀ya Gadi, Ramotu ni Gileadi pẹlu àgbegbe rẹ̀, ilu àbo fun apania; ati Mahanaimu pẹlu àgbegbe rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ara ẹ̀yà Gádì ní wọ́n ti fún wọn ní Rámótìa ní Gílíádì (tí ó jẹ́ ìlú ààbò fún apànìyàn), Máhánáímù,