Joshua 22:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Joṣua bá súre fún wọn, lẹ́yìn náà, ó ní kí wọ́n pada lọ sí ilẹ̀ wọn, wọ́n sì pada lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni Joṣua sure fun wọn, o si rán wọn lọ: nwọn si lọ sinu agọ́ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Jóṣúà súre fún wọn, ó sì jẹ́ kí wọn máa lọ sí ilẹ̀ wọn.