Joshua 24:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni àwọn eniyan náà dáhùn, wọ́n ní, “Kí á má rí i pé a kọ OLUWA sílẹ̀, a sì ń bọ oriṣa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia na dahùn, nwọn si wipe, Ki a má ri ti awa o fi kọ̀ OLUWA silẹ, lati sìn oriṣa;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn sì dáhùn pé, “Kí a má ri tí àwa yóò fi kọ OLÚWA sílẹ̀ láti sin òrìṣà.!