Joshua 24:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli sin OLUWA ní gbogbo àkókò tí Joṣua fi wà láàyè, ati ní àkókò àwọn àgbààgbà tí wọ́n ṣẹ́kù lẹ́yìn Joṣua, tí wọ́n mọ gbogbo ohun tí OLUWA ṣe fún Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Israeli si sìn OLUWA ni gbogbo ọjọ́ Joṣua, ati ni gbogbo ọjọ́ awọn àgba ti o wà lẹhin Joṣua, ti o si mọ̀ gbogbo iṣẹ OLUWA, ti o ṣe fun Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísírẹ́lì sì sin OLÚWA ní gbogbo ọjọ́ ayé Jóṣúà àti ní gbogbo ọjọ́ àwọn àgbààgbà tí ó pẹ́ ju Jóṣúà lọ àti àwọn tó ti rí ohun gbogbo tí OLÚWA ti ṣe fún Ísírẹ́lì.