Joshua 3:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn ọjọ́ kẹta, gbogbo àwọn olórí wọn lọ káàkiri àgọ́ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe lẹhin ijọ́ mẹta, ni awọn olori là ãrin ibudó já;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn ọjọ́ kẹ́ta àwọn olórí la àárin ibùdó já.