Joshua 5:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Joṣua bá fi akọ òkúta ṣe abẹ, ó fi kọ ilà abẹ́ fún gbogbo ọkunrin Israẹli ní Gibeati Haaraloti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joṣua si ṣe abẹ okuta, o si kọ awọn ọmọ Israeli nilà, ni Gibeati-haaralotu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni Jóṣúà sì ṣe abẹ akọ òkúta, ó sì kọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ilà, ní Gíbíátì-Hárálótù.