Joshua 6:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA wà pẹlu Joṣua, òkìkí rẹ̀ sì kàn ní gbogbo ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni OLUWA wà pẹlu Joṣua; okikí rẹ̀ si kàn ká gbogbo ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni OLÚWA wà pẹ̀lú Jóṣúà; òkìkí rẹ̀ sì kàn ká gbogbo ilẹ̀ náà.