Joshua 9:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn nígbà tí àwọn ará Gibeoni gbọ́ ohun tí Joṣua ṣe sí ìlú Jẹriko ati Ai,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati awọn ara Gibeoni gbọ́ ohun ti Joṣua ṣe si Jeriko ati si Ai,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ènìyàn Gíbíónì gbọ́ ohun tí Jóṣúà ṣe sí Jẹ́ríkò àti Áì,