Judges 11:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹfuta bá rékọjá lọ sọ́dọ̀ àwọn ará Amoni láti bá wọn jagun, OLUWA sì fún un ní ìṣẹ́gun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jefta si kọja lọ sọdọ awọn ọmọ Ammoni, lati bá wọn jà; OLUWA si fi nwọn lé e lọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́fítà sì jáde lọ láti bá àwọn ará Ámónì jagun, OLÚWA sì fi wọ́n lé e lọ́wọ́.