Judges 11:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ó yá, àwọn ará Amoni gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe lẹhin ijọ́ melokan, awọn ọmọ Ammoni bá Israeli jagun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní àsìkò kan, nígbà tí àwọn ará Ámónì dìde ogun sí àwọn Ísírẹ́lì,