Judges 14:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó pada wálé wá sọ fún baba ati ìyá rẹ̀, ó ní, “Mo rí ọ̀kan ninu àwọn ọmọbinrin ará Filistia ní Timna, ó wù mí, ẹ jọ̀wọ́, ẹ fẹ́ ẹ fún mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si gòke wá, o si sọ fun baba on iya rẹ̀, o si wipe, Emi ri obinrin kan ni Timna ninu awọn ọmọbinrin awọn Filistini: njẹ nitorina ẹ fẹ́ ẹ fun mi li aya.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó darí (padà sílé) dé, ó sọ fún àwọn òbí rẹ̀ (baba àti ìyá rẹ̀) pé, “Mo rí obìnrin Fílístínì kan ní Tímínà: báyìí ẹ fẹ́ ẹ fún mi bí aya mi”