Judges 15:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Samsoni bá sọ fún wọn pé, “Bí ó bá jẹ́ pé bí ẹ óo ti ṣe nìyí n óo gbẹ̀san lára yín, lẹ́yìn náà, n óo fi yín sílẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Samsoni si wi fun wọn pe, Bi ẹnyin ba ṣe irú eyi, dajudaju emi o gbẹsan lara nyin, lẹhin na emi o si dẹkun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sámúsónì sọ fún un pé, “Nítorí pé ẹ̀yin ṣe èyí, èmi kò dẹṣẹ̀ (dúró) títí èmi yóò fi gbẹ̀ṣan mi lára yín.”