Judges 17:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọkunrin kan wà ní agbègbè olókè ti Efuraimu tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Mika.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ỌKUNRIN kan si wà ni ilẹ òke Efraimu, orukọ ẹniti ijẹ Mika.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Míkà láti agbégbé òkè Éfúráímù