Judges 17:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mika fi ọdọmọkunrin náà jẹ alufaa, ó sì ń gbé ilé Mika.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mika si yà ọmọ Lefi na sọ̀tọ, ọmọkunrin na si wa di alufa rẹ̀, o si wà ninu ile Mika.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Míkà ya ará Léfì náà sí mímọ́, ọ̀dọ́mọkùnrin náà sì di àlùfáà rẹ̀, ó sì ń gbé ilé rẹ̀.