Judges 18:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ará Dani dá a lóhùn, wọ́n ní, “Má jẹ́ kí àwọn eniyan gbọ́ ohùn rẹ láàrin wa, kí àwọn tí inú ń bí má baà pa ìwọ ati gbogbo ìdílé rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Dani si wi fun u pe, Máṣe jẹ ki a gbọ́ ohùn rẹ lãrin wa, ki awọn oninuṣùṣu ki o má bã kọlù nyin, iwọ a si sọ ẹmi rẹ nù, ati ẹmi awọn ara ile rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọkùnrin Dánì náà dáhùn pé, “Má se bá wa jiyàn, tàbí àwọn oníbínú fùfù ènìyàn lè kọlù yín, ìwọ àti àwọn ìdílé yóò sì sọ ẹ̀mí yín nù.”
Recommended Reading