Judges 18:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ará Dani bá ń bá tiwọn lọ, nígbà tí Mika rí i pé wọ́n lágbára ju òun lọ, ó pada sílé rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Dani si ba ọ̀na wọn lọ: nigbati Mika si ri i pe, nwọn lagbara jù on lọ, on si yipada, o si pada lọ sinu ile rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọkùnrin Dánì náà sì bá ọ̀nà wọn lọ. Nígbà tí Míkà rí í pé wọ́n lágbára púpọ̀ fún òun, ó sì padà sí ilé rẹ̀.