Judges 19:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èdè-àìyedè kan bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn mejeeji, obinrin yìí bá kúrò lọ́dọ̀ ọkunrin náà, ó lọ sí ilé baba rẹ̀ ní Bẹtilẹhẹmu, ó sì ń gbé ibẹ̀ fún nǹkan bí oṣù mẹrin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Àle rẹ̀ na si ṣe panṣaga si i, o si lọ kuro lọdọ rẹ̀ si ile baba rẹ̀ si Beti-lehemu-juda, o si wà ni ibẹ̀ ni ìwọn oṣù mẹrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àlè rẹ̀ náà jẹ́ aláìṣòótọ́ sí i, òun fi sílẹ̀, ó sì padà lọ sí ilé baba rẹ̀ ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti Júdà. Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti lo oṣù mẹ́rin ní ilé baba rẹ̀