Judges 19:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí wọ́n rí i sì ń wí pé, “A kò rí irú èyí rí láti ọjọ́ tí àwọn ọmọ Israẹli ti jáde láti ilẹ̀ Ijipti títí di àkókò yìí, ọ̀rọ̀ náà tó àpérò, ẹ gbìmọ̀ ohun tí a ó ṣe, kí ẹ sì sọ̀rọ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, ti gbogbo awọn ẹniti o ri i wipe, A kò ti ìhu irú ìwa bayi, bẹ̃li a kò ti iri i lati ọjọ́ ti awọn ọmọ Israeli ti gòke ti ilẹ Egipti wá titi o fi di oni-oloni: ẹ rò o, ẹ gbimọ̀, ki ẹ si sọ̀rọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ẹni tí ó rí i sì wí pé, “A kò ti rí i, bẹ́ẹ̀ a kò tí ì ṣe irú nǹkan yìí rí, kì í ṣe láti ọjọ́ tí Ísírẹ́lì ti jáde tí Éjíbítì wá títí di òní olónìí. Ẹrò ó wò, ẹ gbìmọ̀ràn kí ẹ sọ fún wa ohun tí a ó ò ṣe!”