Judges 2:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, wọ́n ń bọ oriṣa Baali.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Israeli si ṣe buburu niwaju OLUWA, nwọn si nsìn Baalimu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe ohun tí ó burú níwájú OLÚWA, wọ́n sì ń sin òrìṣà Bálímù.