Judges 2:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti ìsinsìnyìí lọ n kò ní lé èyíkéyìí, ninu àwọn orílẹ̀-èdè tí ó kù kí Joṣua tó kú, jáde fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi pẹlu ki yio lé ọkan jade mọ́ kuro niwaju wọn ninu awọn orilẹ-ède, ti Joṣua fisilẹ nigbati o kú:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kì yóò lé ọ̀kankan nínú àwọn orílẹ̀-èdè tí Jóṣúà fi sílẹ̀ nígbà tí ó kú jáde.