Judges 20:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli bá gbéra ní òwúrọ̀ ọjọ́ keji, wọ́n lọ pàgọ́ sí òdìkejì Gibea,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Israeli si dide li owurọ̀, nwọn si dótì Gibea.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísirẹ́lì dìde ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, wọ́n sì dóti Gíbíà (wọ́n tẹ̀gùn sí ẹ̀bá Gíbíà).