Judges 20:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli bá fi àwọn eniyan pamọ́ ní ibùba, yípo gbogbo Gibea.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Israeli si yàn awọn enia ti o ba yi Gibea ká.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì yàn àwọn ènìyàn tí ó lúgọ (sápamọ́) yí Gíbíà ká.