Judges 20:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ẹ̀yà Bẹnjamini gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ti kó ara wọn jọ ní Misipa. Àwọn ọmọ Israẹli bèèrè lọ́wọ́ ọmọ Lefi náà pé, “Sọ fún wa, báwo ni nǹkan burúkú yìí ti ṣe ṣẹlẹ̀?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
(Awọn ọmọ Benjamini si gbọ́ pe awọn ọmọ Israeli gòke lọ si Mispa.) Awọn ọmọ Israeli si wipe, Sọ fun wa, bawo ni ti ìwabuburu yi ti ri?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(Àwọn ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì gbọ́ wí pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóòkù ti gòkè lọ sí Mísípà). Nígbà náà ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wí pé, “Ẹ sọ fún wa báwo ni iṣẹ́ búburú ṣe ṣẹlẹ̀.”