Judges 20:46 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí wọ́n kú ninu àwọn ọmọ Bẹnjamini ní ọjọ́ náà jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹẹdẹgbaata (25,000); gbogbo wọ́n jẹ́ akikanju jagunjagun tí ń lo idà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni gbogbo awọn ni o ṣubu ni ijọ́ na ninu awọn ara Benjamini jẹ́ ẹgba mejila ọkunrin o le ẹgbẹrun ti o nkọ idà; gbogbo awọn wọnyi li akọni ọkunrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ náà ẹgbàá méjìlá ó lé ẹgbẹ̀rún (25,000) jagunjagun Bẹ́ńjámínì tí ń fi idà jagun ní ó ṣubú, gbogbo wọn jẹ́ akọni ológun.