Judges 21:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àánú àwọn ọmọ Bẹnjamini bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àwọn ọmọ Israẹli nítorí pé OLUWA ti dín ọ̀kan kù ninu ẹ̀yà Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia na si kãnu nitori Benjamini, nitoripe OLUWA ṣe àlàfo ninu awọn ẹ̀ya Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn náà sì káàánú nítorí ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, nítorí OLÚWA fi àlàfo kan sílẹ̀ nínú àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì.