Judges 3:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, ilẹ̀ náà wà ní alaafia fún ogoji ọdún, lẹ́yìn náà, Otinieli ọmọ Kenasi ṣaláìsí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ na si simi li ogoji ọdún. Otnieli ọmọ Kenasi si kú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ náà sì wà ní àlàáfíà fún ogójì ọdún títí tí Ótíníẹ́lì fi kú.