Judges 3:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, wọ́n gbàgbé OLUWA Ọlọrun wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bọ oriṣa Baali ati Aṣerotu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Israeli si ṣe eyiti o buru li oju OLUWA, nwọn si gbàgbé OLUWA Ọlọrun wọn, nwọn si nsìn Baalimu ati Aṣerotu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe èyí tí ó burú níwájú OLÚWA. Wọ́n gbàgbé OLÚWA Ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń sin Báálímù àti Áṣérótù.