Judges 5:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Debora ati Baraki ọmọ Abinoamu bá kọrin ní ọjọ́ náà pé:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBANA ni Debora on Baraki ọmọ Abinoamu kọrin li ọjọ́ na, wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Dèbórà àti Bárákì ọmọ Ábínóámù kọ orin ní ọjọ́ náà wí pé: