Judges 5:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ tẹ́tí sí ohùn àwọn akọrin lẹ́bàá odò, ibẹ̀ ni wọ́n ti ń sọ̀rọ̀ nípa ìṣẹ́gun OLUWA, ọ̀rọ̀ ìṣẹ́gun àwọn eniyan rẹ̀ ní Israẹli. Àwọn eniyan OLUWA sì yan jáde láti ẹnubodè ìlú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọ̀na jijìn si ariwo awọn tafàtafa nibiti a gbé nfà omi, nibẹ̀ ni nwọn o gbé sọ iṣẹ ododo OLUWA, ani iṣẹ ododo ijọba rẹ̀ ni Israeli. Nigbana ni awọn enia OLUWA sọkalẹ lọ si ibode.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ariwo àwọn tafàtafà, ní ibi tí a gbé ń fa omi. Wọ́n ń sọ ti iṣẹ́ òdodo OLÚWA níbẹ̀, àní iṣẹ òdodo ìjọba rẹ̀ ní Ísírẹ́lì. “Nígbà náà ni àwọn ènìyàn OLÚWA sọ̀ kalẹ̀ lọ sí ibodè.