Judges 5:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn akikanju yòókù bẹ̀rẹ̀ sí yan bọ̀, àwọn eniyan OLUWA náà sì ń wọ́ bọ̀, láti gbógun ti alágbára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni iyokù ninu awọn ọlọ̀tọ ati awọn enia sọkalẹ; OLUWA sọkalẹ sori awọn alagbara fun mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà náà ni ó fi àwọn tókù jọba lórí àwọn ènìyàn; OLÚWA fún mi ìjọba lórí àwọn alágbára.