Judges 5:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Gileadi dúró ní ìlà oòrùn odò Jọdani, kí ló dé tí ẹ̀yà Dani fi dúró ní ìdí ọkọ̀ ojú omi? Àwọn ẹ̀yà Aṣeri jókòó létí òkun, wọ́n wà ní ẹsẹ̀ odò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gileadi joko loke odò Jordani: ẽṣe ti Dani fi joko ninu ọkọ̀? Aṣeri joko leti okun, o si ngbé ebute rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gílíádì jókòó ní òkè odò Jọ́dánì. Èéṣe tí Dánì fi jókòó nínú ọkọ̀ ojú omi? Ásérì jòkòó ní etí bèbè òkun, ó sì n gbé èbúté rẹ̀.