Judges 5:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Sebuluni fi ẹ̀mí wọn wéwu dójú ikú, bẹ́ẹ̀ náà sì ni àwọn ọmọ Nafutali, wọ́n fi ẹ̀mí ara wọn wéwu ninu pápá, lójú ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sebuluni li awọn enia, ti o fi ẹmi wọn wewu ikú, ati Naftali, ni ibi giga pápa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn Ṣébúlúnì fi ẹ̀mí wọn wéwu ikú; bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ènìyàn Náfítalì ní ibi gíga pápá.