Judges 5:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ fi ìyìn fún OLUWA, nítorí pé, àwọn olórí ni wọ́n ṣiwaju ní Israẹli, àwọn eniyan sì fi tọkàntọkàn fa ara wọn kalẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori bi awọn olori ti ṣaju ni Israeli, nitori bi awọn enia ti fi tinutinu wá, ẹ fi ibukún fun OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí bí àwọn olórí ti ṣíwájú ní Ísírẹ́lì, nítorí bi àwọn ènìyàn ti fi tọkàntọkàn wa, Ẹ fi ìbùkún fún OLÚWA!