Judges 5:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Láti ojú ọ̀run ni àwọn ìràwọ̀ ti ń jagun, àní láti ààyè wọn lójú ọ̀nà wọn, ni wọ́n ti bá Sisera jà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn jà lati ọrun wá, awọn irawọ ni ipa wọn bá Sisera jà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìràwọ̀ já láti ojú ọ̀run wá láti ibùjókòó wọn ni wọ́n ti bá Ṣísérà jà.