Judges 5:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Odò Kiṣoni kó wọn lọ, odò Kiṣoni, tí ó kún àkúnya. Máa yan lọ, ìwọ ọkàn mi, máa fi agbára yan lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Odò Kiṣoni gbá wọn lọ, odò igbani, odò Kiṣoni. Hã ọkàn mi, ma yan lọ ninu agbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Odò Kísónì agbá wọn lọ, odò àtijọ́ náà, odò Kíṣónì. Má a yan lọ ìwọ ọkàn mi, jẹ́ alágbára pẹ̀lú!