Judges 5:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ẹṣin sáré dé, pẹlu ariwo pátákò ẹsẹ̀ wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí fi ẹsẹ̀ kilẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni patako ẹsẹ̀ ẹṣin kì ilẹ, nitori ire-sisá, iré-sisá awọn alagbara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni pátakò ẹṣẹ̀ ẹsin ki ilẹ̀, nítorí eré sísá, eré sísá àwọn alágbára wọn.